It's Thursday, July 18, 2019 - 10:30 PM in Nigeria.

 • NigeriaWorldToday [Home]
 • Newspapers & Dailies
 • Facts, Figures & Information
 • Articles
 • States & Local Government
 • Industries & Businesses
 • Marketplaces
 • Safety & Security
 • Financial Scams & Fraudsters
 • History
 • First Nigerian
 • Symbols, Signs & Logos
 • Constitution/Law
 • Rankings
 • Predictions
 • Health
 • Education
 • Human Interest Stories
 • Sport
 • People Responses
 • Entertainment
 • Funny Naija

 • NigeriaWorldToday [Home] > All about Nigeria > National Anthem of Nigerian in Yoruba, Igbo & Hausa Languages

  National Anthem of Nigerian in Yoruba, Igbo & Hausa Languages


  Yoruba, Hausa and Igbo
  Nigerian Heroes Past – The Real Compatriots

  Nigerian National Anthem Lyrics in Yoruba Language

  Ese Kinni – First Stanza

  Dide eyin ara
  Wa je-pe Naijiria,
  ka fife sin ‘lewa
  pelu okun ati ‘gbagbo
  Ki ise awon akoni wa
  ko ma se ja sa-san,
  Ka sin tokan-tara
  ile tominira wa,
  alafia so-dokan.

  Ese Keji – Second Stanza

  Olorun Eleda
  To ipa ona wa
  F’ona han asaaju
  K’odo wa m’otito
  K’ododo at’ife po sii
  K’aye won je pipe
  So won d’eni giga
  K’alafia oun eto le
  Joba ni ‘le wa

  Ileri – The Pledge

  Mo se ileri fun Orile-Ede mi Naijiria,
  Lati je olododo, eniti o see f’okan tan
  Ati olotito eniyan
  Lati sin in pelu gbogbo agbara mi,
  Lati sa ipa mi gbogbo fun isokan re
  Ati lati gbe e ga fun iyi ati ogo re.
  Ki Olorun ran mi l’owo

  Nigerian National Anthem Lyrics in Igbo Language

  Zọlié ndi àlà anyị
  Záá òkù Naijiria
  Ka ànyị jee ózi n’okwukwe
  N’íké, n’ịhụnanya
  Ka íké ndị odogwu ànyị kpàrà
  Ghàrá ịla n’íyì
  Ji óbì, n’íké jee ozi
  Ótù obodo nwe ònwé ya
  Ùdó na idi n’ótù

  Nigerian National Anthem Lyrics in Hausa Language

  Yaku ‘yan Nijeriya ku farka;
  Ku amsa kiran Nijeriya;
  Domin mu taimaki ƙasarmu ta haihuwa;
  Don aiki ga ƙasata cikin soyayya da riƙon gaskiya;
  Domin gudumawar da shuwagabaninmu ‘yan kishin ƙasa suka bada;
  kada ta zama a banza;
  Muyi aiki da zuciya ɗaya da girmamawa a gareta;
  Domin ta kasance ƙasa ɗaya mai yanci ga kowa tare da haɗin kai da zaman lafiya.


  Back to
  the top